Kaabo si ikanni giga ju lo laiye! O ga to kilomita 18,94 (nkan bi maili 11,77), ati opolopo igbadun ilosokesodo. Farabale ki o le gbadun re.
Fun atejade didara ati awon ironlowo isofuni, wo abala yi lo si isale tabi ko o lo ategun, ti yoo fun o ni iluja yiyara bi ina lofe.
Ohun iyalenu. Pada si ibere? Lo si oke abala (a ma a duro de o), lo etegun tabi te Ctrl ati Pos1.
Fun awon elomiran, atejade didara wa fun won. Ikanni yi wa fun iwalejin CSS. Nitori idi yi, awon ikalowoko kan yo o wa. Ona ti a gba seto ikanni yi rorun lati loye:
Bi o ba ni awon atunse tabi awon ohun elo giga miran ti ona isise re ni itewogba gbogbogbo, fi ranse si info@worlds-highest-website.com. O see se ki o gba ebun.
WHWS ni an gbe sori afefe lati owo ogbeni akosemose ti oruko re n je Jens Oliver Meiert ati asiri “Flying Standardistas Club” aworan: Alessandro Lettieri.